Onídájọ́ 5:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bẹ́ẹ̀ ni kí ó jẹ́ kí gbogbo àwọn ọ̀ta rẹ kí ó ṣègbé Olúwa!Ṣùgbọ́n jẹ́ kí àwọn tí ó fẹ́ ọ ràn bí oòrùn.nígbà tí ó bá yọ nínú agbára rẹ̀.”Ilẹ̀ náà sì simi ní ogójì ọdún

Onídájọ́ 5

Onídájọ́ 5:27-31