Onídájọ́ 13:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkùnrin ará Sórà kan wà, orúkọ rẹ̀ a máa jẹ́ Mánóà láti ẹ̀yà Dánì. Aya rẹ̀ yàgàn kò sì bímọ.

Onídájọ́ 13

Onídájọ́ 13:1-12