Onídájọ́ 13:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì tún ṣe ohun tí ó burú ní ojú Olúwa, Olúwa sì fi wọ́n lé àwọn ará Fílístínì lọ́wọ́ fún ogójì (40) ọdún.

Onídájọ́ 13

Onídájọ́ 13:1-8