Onídájọ́ 1:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Adoni-Bésékì sá àṣálà, ṣùgbọ́n ogun Ísírẹ́lì lépa rẹ̀ wọ́n sì bá a, wọ́n sì gé àwọn àtàǹpàkò ọwọ́ àti ẹṣẹ̀ rẹ̀.

Onídájọ́ 1

Onídájọ́ 1:1-11