Onídájọ́ 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní Béṣékì ni wọ́n ti rí Adoni-Bésékì (Olúwa mi ní Béṣékì), wọ́n sì bá a jagun, wọ́n sì ṣẹ́gun àwọn ará Kénánì àti Párísì.

Onídájọ́ 1

Onídájọ́ 1:1-8