Nọ́ḿbà 35:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìlú mẹ́fà yìí yóò jẹ́ ìlú ìsásí fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, fún àlejò àti ẹnikẹ́ni tí ó bá ń gbé láàrin wọn, kí ẹnikẹ́ni tí ó bá pa ènìyàn ní àìmọ̀ sá lọ ṣíbẹ̀.

Nọ́ḿbà 35

Nọ́ḿbà 35:13-19