Nọ́ḿbà 35:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yan ìlú mẹ́ta ní ìhà ti Jọ́dánì, kí ẹ sì yan ìlú mẹ́ta ní ìhà Kénánì tí yóò máa jẹ́ ìlú ìsásí.

Nọ́ḿbà 35

Nọ́ḿbà 35:9-15