Nọ́ḿbà 2:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì se gbogbo ohun tí Olúwa pa láṣẹ fún Mósè, báyìí ni wọ́n ṣe pa ibùdó lábẹ́ ọ̀págun wọn, bẹ́ẹ̀ náà sì ni wọ́n ṣe jáde, oníkálùkù pẹ̀lú ẹbí àti ìdílé rẹ̀.

Nọ́ḿbà 2

Nọ́ḿbà 2:29-34