Nọ́ḿbà 2:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n a kò ka àwọn ọmọ Léfì papọ̀ mọ́ àwọn Ísírẹ́lì gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pa á láṣẹ fún Mósè.

Nọ́ḿbà 2

Nọ́ḿbà 2:31-34