Nehemáyà 3:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Málíkíjà ọmọ Hárímù àti Háṣúbù ọmọ Páhátì—Móábù tún ẹ̀gbẹ́ kejì ṣe àti Ilé-ìṣọ́ Ìléru.

Nehemáyà 3

Nehemáyà 3:6-14