Nehemáyà 3:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ẹ̀gbẹ́ èyí Jédáyà ọmọ Hárúmáfì tún èyí tí ó wà ní ọ̀ọ́kán ilé rẹ̀ mọ, Hátúsì ọmọ Háṣábínéjà sì tún tí ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ mọ.

Nehemáyà 3

Nehemáyà 3:2-13