Nehemáyà 2:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

mo sì dá ọba lóhùn pé, “Ti ó bá wu ọba, tí ìránṣẹ́ rẹ bá sì rí ojú rere ní ojú rẹ, jẹ́ kí ó rán mi lọ sí ìlú náà ní Júdà ní bi tí a sin àwọn baba mi nítorí kí èmi lè tún un kọ́.”

Nehemáyà 2

Nehemáyà 2:2-15