Nehemáyà 2:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba wí fún mi pé, “Kí ni ìwọ ń fẹ́?”Nígbà náà, ni mo gbàdúrà sí Ọlọ́run ọ̀run,

Nehemáyà 2

Nehemáyà 2:1-9