Míkà 2:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí ó ń fọ ọ̀nà yóò lọ sókè níwájú wọn;Wọn yóò fọ láti ẹnu-bodè, wọn yóò sì jáde lọ.Àwọn ọba wọn yóò sì kọjá lọ níwájú wọn, Olúwa ni yóò sì ṣe olórí wọn.”

Míkà 2

Míkà 2:4-13