Míkà 2:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi yóò kó gbogbo yín jọ, ìwọ Jákọ́bù;Èmi yóò gbá ìyókù Ísírẹ́lì jọ.Èmi yóò kó wọn jọ pọ̀ gẹ́gẹ́ bí àgùntàn nínú agbo ẹran,gẹ́gẹ́ bí ọ̀wọ́ ẹran nínú agbo wọn,ibẹ̀ yóò sì pariwo nítorí ọ̀pọ̀ ènìyàn.

Míkà 2

Míkà 2:4-13