Mátíù 5:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe fi orí rẹ búra, nítorí ìwọ kò lè sọ irun ẹyọ kan di funfun tàbí di dúdú.

Mátíù 5

Mátíù 5:32-44