Mátíù 5:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tàbí ìfi-ayé-búra, nítorí àpótí ìtìsẹ̀ Ọlọ́run ni; tàbí Jerúsálémù, nítorí olórí ìlú Ọba Ńlá ni.

Mátíù 5

Mátíù 5:26-36