Mátíù 5:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“A ti wí pẹ̀lú pé, ‘Ẹnikẹ́ni tí ó bá kọ aya rẹ̀ sílẹ̀ gbọdọ̀ fún un ní ìwé-ẹ̀rí ìkọ̀sílẹ̀.’

Mátíù 5

Mátíù 5:21-41