Mátíù 5:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ọwọ́ rẹ ọ̀tún bá mú ọ dẹ́ṣẹ̀ gé e kúrò, kí ó sì sọ ọ́ nù. Ó sàn kí ẹ̀ya ara rẹ kan ṣègbé ju kí gbogbo ara rẹ lọ sínú iná ọ̀run àpáàdì.

Mátíù 5

Mátíù 5:27-36