Mátíù 26:75 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Pétérù rántí nǹkan tí Jésù ti sọ pé, “Kí àkùkọ tóó kọ, ìwọ yóò sẹ́ mi nígbà mẹ́ta.” Òun sì bọ́ sí òde, ó sọkún kíkorò.

Mátíù 26

Mátíù 26:65-75