Mátíù 26:74 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pétérù sì tún bẹ̀rẹ̀ sí íbúra ó sì fi ara rẹ̀ ré wí pé, “Mo ní èmi kò mọ ọkùnrin yìí rárá.”Lójú kan náà àkùkọ sì kọ.

Mátíù 26

Mátíù 26:67-75