Mátíù 19:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sọ èyí fún yín pé, ẹni tí ó bá kọ aya rẹ̀ sílẹ̀, láìṣe pé nítorí àgbèrè, tí ó sì fẹ́ òmíràn, ó ṣe panṣágà.”

Mátíù 19

Mátíù 19:5-16