Mátíù 19:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù dáhùn pé, “Mósè yọ̀ǹda kí ẹ kọ aya yín sílẹ̀ nítorí ọkàn yín le. Ṣùgbọ́n kò rí bẹ́ẹ̀ láti àtètèkọ́ṣe.

Mátíù 19

Mátíù 19:1-9