Mátíù 15:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì dá wọn lóhùn pé, “È é ha ṣe tí ẹ̀yin fi rú òfin Ọlọ́run, nítorí àṣà yín?

Mátíù 15

Mátíù 15:2-9