Mátíù 15:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

wọn béèrè pé, “Èé se tí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ fi ń ṣe àìgbọ́ràn sí àwọn àṣà àtayébáyé Júù? Nítorí tí wọn kò wẹ ọwọ́ wọn kí wọ́n tó jẹun!”

Mátíù 15

Mátíù 15:1-9