Mátíù 13:51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù bí wọn léèrè pé, “Ǹjẹ́ gbogbo nǹkan wọ̀nyí yé yín.”Wọ́n dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, ó yé wa.”

Mátíù 13

Mátíù 13:42-58