Mátíù 13:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn ó sì ju àwọn ènìyàn búburú sínú iná ìléru náà, ní ibi ti ẹkún àti ìpayínkeke yóò gbé wà.”

Mátíù 13

Mátíù 13:47-56