Mátíù 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Júdà ni baba Pérésì àti Ṣérà,Támárì sì ni ìyá rẹ̀,Pérésì ni baba Ésírónù:Ésírónù ni baba Rámù;

Mátíù 1

Mátíù 1:1-7