Mátíù 1:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n òun kò mọ̀ ọ́n títítí ó fi bí ọmọkùnrin, òun sì sọ orúkọ rẹ̀ ní Jésù.

Mátíù 1

Mátíù 1:22-25