Mátíù 1:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Jósẹ́fù jí lójú oorun rẹ̀, òun ṣe gẹ́gẹ́ bí ańgẹ́lì Olúwa ti pàṣẹ fún un. Ó mú Màríà wá sílé rẹ̀ ní aya.

Mátíù 1

Mátíù 1:19-25