Máàkù 15:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní báyìí, nígbà àjọ, gẹ́gẹ́ bí àsà, òun a máa dá òǹdè kan sílẹ̀ fún àwọn, ẹnikẹ́ni tí wọ́n bá béèrè fún.

Máàkù 15

Máàkù 15:5-9