Máàkù 14:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ìbá tà á ju owó iṣẹ́ ọdún kan lọ, kí ó sì fi owó rẹ̀ ta àwọn talákà lọ́rẹ.” Báyìí ni wọ́n ń fi ọ̀rọ̀ gún obìnrin náà lára.

Máàkù 14

Máàkù 14:2-7