Máàkù 14:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn kan nínú àwọn tí ó jókòó ti tábìlì kún fún ìbànújẹ́. Wọ́n sì ń bi ara wọn pé, “Nítorí kí ni a ṣe fi òróró yìí ṣòfò?

Máàkù 14

Máàkù 14:2-7