Lúùkù 9:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì wí fún un, pé, “Má ṣe dá a lẹ́kun mọ́: nítorí ẹni tí kò bá lòdì síi yín, ó wà fún yín.”

Lúùkù 9

Lúùkù 9:48-60