Lúùkù 9:49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jòhánù sì dáhùn ó sì wí fún un pé, “Olùkọ́, àwá rí ẹnìkan ó ń fi orúkọ rẹ lé àwọn ẹ̀mí èsù jáde; àwa sì dá a lẹ́kun, nítorí tí kò bá wa tọ̀ ọ́ lẹ́yìn.”

Lúùkù 9

Lúùkù 9:48-55