Lúùkù 9:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohùn kan sì ti inú ìkùukùu wá wí pé, “Èyí yìí ni àyànfẹ́ ọmọ mi: ẹ máa gbọ́ tirẹ̀.”

Lúùkù 9

Lúùkù 9:34-36