Lúùkù 7:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ayánilówó kan wà tí ó ní ajigbésè méjì: ọ̀kan jẹ ẹ́ ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta owó idẹ, èkejì sì jẹ ẹ́ ní àádọ́ta.

Lúùkù 7

Lúùkù 7:40-42