Lúùkù 5:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́hìn èyí, Jésù jáde lọ, ó sì rí agbowó òde kan tí à ń pè ní Léfì ó jòkòó sí ibi tí ó ti ń gba owó òde, Jésù sì wí fún un pé “Tẹ̀lé mi,”

Lúùkù 5

Lúùkù 5:21-30