Lúùkù 5:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnu sì ya gbogbo wọn, wọ́n sì yin Ọlọ́run lógo, ẹ̀rù sì bà wọ́n, wọ́n ń wí pé, “Àwá rí ohun abàmì lónì-ín.”

Lúùkù 5

Lúùkù 5:24-33