Lúùkù 4:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo wọn sì jẹ́rìí rẹ̀, háà sì ṣe wọ́n sí ọ̀rọ̀ oore-ọ̀fẹ́ tí ń jáde ní ẹnu rẹ̀, wọ́n sì wí pé, “Ọmọ Jósẹ́fù kọ́ yìí?”

Lúùkù 4

Lúùkù 4:21-23