Lúùkù 4:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì kún fún Ẹ̀mí Mímọ́, ó padà ti Jọ́dánì wá, a sì ti ọwọ́ Ẹ̀mí darí rẹ̀ sí ijù;

Lúùkù 4

Lúùkù 4:1-11