Lúùkù 3:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí í ṣe ọmọ Énósì,tí í ṣe ọmọ Sétì, tí í ṣe ọmọ Ádámù,tí í ṣe ọmọ Ọlọ́run.

Lúùkù 3

Lúùkù 3:34-38