Lúùkù 21:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àyà àwọn ènìyàn yóò máa já fún ìbẹ̀rù, àti ìrètí nǹkan wọ̀nyí tí ń bọ̀ sórí ayé: nítorí àwọn agbára ọ̀run ni a ó mì tìtì.

Lúùkù 21

Lúùkù 21:18-36