Lúùkù 21:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àmì yóò sì wà ní ọ̀run, àti ní òṣùpá, àti ní ìràwọ̀; àti lórí ilẹ̀ ayé ìdààmú fún àwọn orílẹ̀-èdè nínú ìpáyà híhó òkun àti ìgbì-omi.

Lúùkù 21

Lúùkù 21:20-29