Lúùkù 21:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ó sì fi yín hàn láti ọwọ́ àwọn òbí yín wá, àti àwọn arákùnrin, àti àwọn ìbátan, àti àwọn ọ̀ré; on ó sì mú kì a pa nínú yín.

Lúùkù 21

Lúùkù 21:8-25