Lúùkù 16:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ipò-òkú ni ó gbé ojú rẹ̀ sókè, ó ń bẹ nínú ìṣẹ́ oró, ó sì rí Ábúráhámù ní òkèrè, àti Lásárù ní oókan-àyà rẹ̀.

Lúùkù 16

Lúùkù 16:19-25