Lúùkù 16:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ó sì ṣe, alágbe kú, a sì ti ọwọ́ àwọn ańgẹ́lì gbé e lọ sí oókan-àyà Ábúráhámù: ọlọ́rọ̀ náà sì kú pẹ̀lú, a sì sin ín;

Lúùkù 16

Lúùkù 16:19-31