Lúùkù 14:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí bẹ́ẹ̀ kọ́, nígbà tí onítọ̀hún bá sì wà ní òkèrè, òun a rán ikọ̀ sí i, a sì bẹ̀rẹ̀ àdéhùn àlààáfíà.

Lúùkù 14

Lúùkù 14:25-35