Lúùkù 14:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Tàbí ọba wo ni ó ń lọ bá ọba mìíràn jà, tí kì yóò kọ́kọ́ jókòó, kí ó sì gbèrò bí yóò lè fi ẹgbàarún-ún pàdégun ẹni tí ń mú ẹgbàawàá bọ̀ wá ko òun lójú?

Lúùkù 14

Lúùkù 14:28-32