Lúùkù 14:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gbogbo wọn sì bẹ̀rẹ̀ ní ohùn kan láti ṣe àwáwí. ‘Èkínní wí fún un pé, mo ra ilẹ̀ kan, mo sì fẹ́ lọ wò ó wò, mo bẹ̀ ọ́ ṣe gáfárà fún mi.’

Lúùkù 14

Lúùkù 14:17-28